Num 32:15 YCE

15 Nitoripe bi ẹnyin ba yipada kuro lẹhin rẹ̀, on o si tun fi wọn silẹ li aginjù; ẹnyin o si run gbogbo awọn enia yi.

Ka pipe ipin Num 32

Wo Num 32:15 ni o tọ