Num 32:28 YCE

28 Mose si paṣẹ fun Eleasari alufa, ati fun Joṣua ọmọ Nuni, ati fun awọn olori ile baba awọn ẹ̀ya ọmọ Israeli, nipa ti wọn.

Ka pipe ipin Num 32

Wo Num 32:28 ni o tọ