39 Awọn ọmọ Makiri ọmọ Manase si lọ si Gileadi, nwọn si gbà a, nwọn si lé awọn ọmọ Amori ti o wà ninu rẹ̀.
Ka pipe ipin Num 32
Wo Num 32:39 ni o tọ