Num 9:18 YCE

18 Nipa aṣẹ OLUWA awọn ọmọ Israeli a ṣí, nipa aṣẹ OLUWA nwọn a si dó: ni gbogbo ọjọ́ ti awọsanma ba simi lori agọ́ na, nwọn a dó.

Ka pipe ipin Num 9

Wo Num 9:18 ni o tọ