Ìwé Òwe 10:23 BM

23 Ibi ṣíṣe a máa dùn mọ́ òmùgọ̀,ṣugbọn ìwà ọgbọ́n ni ayọ̀ fún ẹni tí ó mòye.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 10

Wo Ìwé Òwe 10:23 ni o tọ