Ìwé Òwe 10:32 BM

32 Olódodo mọ ohun tí ó dára láti sọ,ṣugbọn ti eniyan burúkú kò ju ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn lọ.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 10

Wo Ìwé Òwe 10:32 ni o tọ