27 Ọwọ́ ọ̀lẹ kò lè tẹ ohun tí ó ń lé,ṣugbọn ẹni tí ń fi tọkàntọkàn ṣiṣẹ́ yóo ní ọpọlọpọ ọrọ̀.
Ka pipe ipin Ìwé Òwe 12
Wo Ìwé Òwe 12:27 ni o tọ