Ìwé Òwe 13:11 BM

11 Ọrọ̀ tí a fi ìkánjú kójọ kì í pẹ́ dínkù,ṣugbọn ẹni tí ó bá fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ kó ọrọ̀ jọ yóo máa ní àníkún.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 13

Wo Ìwé Òwe 13:11 ni o tọ