Ìwé Òwe 14:35 BM

35 Iranṣẹ tí ó bá hùwà ọlọ́gbọ́n a máa rí ojurere ọba,ṣugbọn inú a máa bí ọba sí iranṣẹ tí ó bá hùwà ìtìjú.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 14

Wo Ìwé Òwe 14:35 ni o tọ