17 Oúnjẹ tí a bá rí lọ́nà èrú máa ń dùn lẹ́nu eniyan,ṣugbọn nígbà tí a bá jẹ ẹ́ tán, ẹnu ẹni a máa kan.
Ka pipe ipin Ìwé Òwe 20
Wo Ìwé Òwe 20:17 ni o tọ