Ìwé Òwe 25:20 BM

20 Bí ẹni tí a bọ́ṣọ rẹ̀ ninu òtútù,tabi tí a da ọtí kíkan sójú egbò rẹ̀,ni ẹni tí à ń kọrin fún ní àkókò tí inú rẹ̀ bàjẹ́.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 25

Wo Ìwé Òwe 25:20 ni o tọ