Ìwé Òwe 25:8 BM

8 Má fi ìwàǹwára fa ẹnikẹ́ni lọ sílé ẹjọ́,nítorí kí ni o óo ṣe nígbà tí aládùúgbò rẹ bá dójútì ọ́.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 25

Wo Ìwé Òwe 25:8 ni o tọ