Ìwé Òwe 28:19 BM

19 Ẹni tí ń ṣiṣẹ́ oko dáradára, yóo ní oúnjẹ pupọ,ṣugbọn ẹni tí ń fi àkókò rẹ̀ ṣòfò yóo di talaka.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 28

Wo Ìwé Òwe 28:19 ni o tọ