Ìwé Òwe 28:28 BM

28 Nígbà tí àwọn eniyan burúkú bá dìde,àwọn eniyan á sá pamọ́,ṣugbọn nígbà tí wọ́n bá parun, olódodo á pọ̀ sí i.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 28

Wo Ìwé Òwe 28:28 ni o tọ