Ìwé Òwe 29:13 BM

13 Ohun tí ó sọ talaka ati aninilára di ọ̀kan náà ni pé,OLUWA ló fún àwọn mejeeji ní ojú láti ríran.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 29

Wo Ìwé Òwe 29:13 ni o tọ