Ìwé Òwe 29:2 BM

2 Nígbà tí olódodo bá di eniyan pataki,àwọn eniyan a máa yọ̀,ṣugbọn nígbà tí eniyan burúkú bá wà lórí oyè,àwọn eniyan a máa kérora.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 29

Wo Ìwé Òwe 29:2 ni o tọ