Ìwé Òwe 31:31 BM

31 Fún un ninu èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀,jẹ́ kí wọn máa yìn ín lẹ́nu ibodè nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 31

Wo Ìwé Òwe 31:31 ni o tọ