Kronika Keji 1:16 BM

16 Láti Ijipti ati Kue ni Solomoni ti ń kó ẹṣin wá, àwọn oníṣòwò tí wọn ń ṣiṣẹ́ fún un ni wọ́n ń ra àwọn ẹṣin náà wá láti Kue.

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:16 ni o tọ