Kronika Keji 1:3 BM

3 Solomoni ati àwọn tí wọ́n péjọ lọ sí ibi gíga tí ó wà ní Gibeoni, nítorí pé àgọ́ ìpàdé Ọlọrun tí Mose, iranṣẹ OLUWA, pa ninu aginjù wà níbẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:3 ni o tọ