Kronika Keji 1:5 BM

5 Pẹpẹ bàbà tí Besaleli ọmọ Uri, ọmọ Huri ṣe, wà níbẹ̀ níwájú àgọ́ OLUWA. Solomoni ati àwọn eniyan rẹ̀ sin OLUWA níbẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:5 ni o tọ