9 Ṣiṣaki bá gbógun ti Jerusalẹmu, ó kó gbogbo ìṣúra ilé OLUWA lọ, ati ti ààfin ọba patapata, ati apata wúrà tí Solomoni ṣe.
Ka pipe ipin Kronika Keji 12
Wo Kronika Keji 12:9 ni o tọ