16 Àwọn ọmọ ogun Israẹli bá sá níwájú àwọn ọmọ ogun Juda, Ọlọrun sì fi wọ́n lé àwọn ọmọ ogun Juda lọ́wọ́.
Ka pipe ipin Kronika Keji 13
Wo Kronika Keji 13:16 ni o tọ