3 Abija kó ogún ọ̀kẹ́ (400,000) akọni ọmọ ogun jọ láti bá Jeroboamu jagun. Jeroboamu náà kó ogoji ọ̀kẹ́ (800,000) akọni ọmọ ogun jọ.
Ka pipe ipin Kronika Keji 13
Wo Kronika Keji 13:3 ni o tọ