Kronika Keji 14:14 BM

14 Wọ́n run gbogbo ìlú tí ó wà ní agbègbè Gerari, nítorí pé ẹ̀rù OLUWA ba àwọn ará ibẹ̀. Wọ́n fi ogun kó gbogbo àwọn ìlú náà nítorí pé ìkógun pọ̀ ninu wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 14

Wo Kronika Keji 14:14 ni o tọ