Kronika Keji 14:9 BM

9 Sera, ará Etiopia, gbógun tì wọ́n pẹlu ẹgbẹrun lọ́nà ẹgbẹrun (1,000,000) ọmọ ogun ati ọọdunrun (300) kẹ̀kẹ́ ogun. Wọ́n sì jagun títí dé Mareṣa.

Ka pipe ipin Kronika Keji 14

Wo Kronika Keji 14:9 ni o tọ