Kronika Keji 15:18 BM

18 Ó kó àwọn nǹkan tí Abija, baba rẹ̀, ti yà sí mímọ́ fún Ọlọrun lọ sinu tẹmpili pẹlu gbogbo nǹkan tí òun pàápàá ti yà sí mímọ́: fadaka, wúrà, ati àwọn ohun èlò.

Ka pipe ipin Kronika Keji 15

Wo Kronika Keji 15:18 ni o tọ