Kronika Keji 16:2 BM

2 Nítorí náà, Asa kó fadaka ati wúrà láti ilé ìṣúra ilé OLUWA ati láti ààfin ranṣẹ sí Benhadadi, ọba Siria tí ó ń gbé Damasku, ó ranṣẹ sí i pé:

Ka pipe ipin Kronika Keji 16

Wo Kronika Keji 16:2 ni o tọ