Kronika Keji 17:12 BM

12 Bẹ́ẹ̀ ni Jehoṣafati ṣe bẹ̀rẹ̀ sí lágbára sí i, ó kọ́ àwọn ilé ìṣọ́ ati àwọn ìlú tí wọn ń kó ìṣúra pamọ́ sí ní Juda;

Ka pipe ipin Kronika Keji 17

Wo Kronika Keji 17:12 ni o tọ