Kronika Keji 17:14 BM

14 Iye àwọn ọmọ ogun tí ó kó jọ nìyí gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn: Adinai ni olórí ogun ẹ̀yà Juda, ó sì ní ọ̀kẹ́ mẹẹdogun (300,000) akọni ọmọ ogun lábẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 17

Wo Kronika Keji 17:14 ni o tọ