Kronika Keji 17:17 BM

17 Àwọn olórí ogun láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini ni: Eliada, akọni ọmọ ogun, ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000) àwọn ọmọ ogun tí wọn ń lo apata ati ọrun ni wọ́n wà lábẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 17

Wo Kronika Keji 17:17 ni o tọ