Kronika Keji 17:2 BM

2 Ó kó àwọn ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi Juda, ó yan olórí ogun fún wọn ní ilẹ̀ Juda ati ní ilẹ̀ Efuraimu tí Asa baba rẹ̀ gbà.

Ka pipe ipin Kronika Keji 17

Wo Kronika Keji 17:2 ni o tọ