Kronika Keji 17:5 BM

5 Nítorí náà OLUWA fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀, gbogbo àwọn ọmọ Juda sì ń san owó orí fún un. Nítorí náà ó di ọlọ́rọ̀ ati ọlọ́lá.

Ka pipe ipin Kronika Keji 17

Wo Kronika Keji 17:5 ni o tọ