Kronika Keji 17:7 BM

7 Ní ọdún kẹta ìjọba rẹ̀, ó pe àwọn marun-un ninu àwọn ìjòyè rẹ̀: Benhaili, Ọbadaya, ati Sakaraya, Netaneli, ati Mikaya, ó rán wọn jáde láti máa kọ́ àwọn eniyan ní ilẹ̀ Juda.

Ka pipe ipin Kronika Keji 17

Wo Kronika Keji 17:7 ni o tọ