1 Nígbà tí Jehoṣafati ọba Juda di ọlọ́rọ̀ ati olókìkí, ó fẹ́ ọmọ Ahabu kí ó lè ní àjọṣepọ̀ pẹlu Ahabu.
Ka pipe ipin Kronika Keji 18
Wo Kronika Keji 18:1 ni o tọ