Kronika Keji 18:17 BM

17 Ọba Israẹli wí fún Jehoṣafati pé, “Ṣé o ranti pé mo ti sọ pé kò sọ àsọtẹ́lẹ̀ rere fún mi rí? Àsọtẹ́lẹ̀ burúkú nìkan ni òun máa ń sọ.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 18

Wo Kronika Keji 18:17 ni o tọ