Kronika Keji 20:10 BM

10 “Nisinsinyii, wo àwọn ọmọ ogun Amoni, ati ti Moabu ati ti Òkè Seiri, àwọn tí o kò jẹ́ kí àwọn ọmọ Israẹli bá jà nígbà tí wọ́n ń bọ̀ láti Ijipti, o kò jẹ́ kí wọ́n pa wọ́n run.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:10 ni o tọ