Kronika Keji 20:13 BM

13 Gbogbo àwọn ọkunrin Juda dúró níwájú OLUWA pẹlu àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ wọn, àwọn aya wọn ati àwọn ọmọ wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:13 ni o tọ