19 Ni àwọn ọmọ Lefi láti inú ìdílé Kohati ati ti Kora bá dìde, wọ́n gbóhùn sókè, wọ́n sì yin OLUWA Ọlọrun Israẹli.
Ka pipe ipin Kronika Keji 20
Wo Kronika Keji 20:19 ni o tọ