Kronika Keji 20:29 BM

29 Ẹ̀rù OLUWA ba ìjọba gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè nígbà tí wọ́n gbọ́ pé OLUWA bá àwọn ọ̀tá àwọn ọmọ Israẹli jagun.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:29 ni o tọ