Kronika Keji 20:33 BM

33 Ṣugbọn kò pa àwọn pẹpẹ ìrúbọ run; àwọn eniyan kò tíì máa fi tọkàntọkàn sin Ọlọrun àwọn baba ńlá wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:33 ni o tọ