Kronika Keji 20:36 BM

36 Wọ́n jọ kan àwọn ọkọ̀ ojú omi tí yóo lọ sí ìlú Taṣiṣi. Wọ́n kan àwọn ọkọ̀ náà ní Esiongeberi.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:36 ni o tọ