Kronika Keji 20:5 BM

5 Jehoṣafati bá dìde dúró láàrin àwọn tí wọ́n ti Juda ati Jerusalẹmu wá sinu tẹmpili, níbi tí wọ́n péjọ sí níwájú gbọ̀ngàn tuntun,

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:5 ni o tọ