Kronika Keji 21:14 BM

14 Wò ó, OLUWA yóo fi àjàkálẹ̀ àrùn ṣe àwọn eniyan rẹ, ati àwọn ọmọ rẹ, ati àwọn aya rẹ ati gbogbo ohun tí o ní.

Ka pipe ipin Kronika Keji 21

Wo Kronika Keji 21:14 ni o tọ