Kronika Keji 22:2 BM

2 Ahasaya jẹ́ ẹni ọdún mejilelogoji, nígbà tí ó jọba; ó sì wà lórí oyè fún ọdún kan ní Jerusalẹmu. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Atalaya, ọmọ ọmọ Omiri.

Ka pipe ipin Kronika Keji 22

Wo Kronika Keji 22:2 ni o tọ