Kronika Keji 22:8 BM

8 Nígbà tí Jehu dé láti pa ilé Ahabu run bí Ọlọrun ti fún un láṣẹ, ó pàdé àwọn ìjòyè Juda ati ọmọ arakunrin Ahasaya tí ó bá Ahasaya wá, ó bá pa wọ́n.

Ka pipe ipin Kronika Keji 22

Wo Kronika Keji 22:8 ni o tọ