Kronika Keji 24:26 BM

26 Àwọn tí wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọba ni Sabadi, ọmọ Ṣimeati ará Amoni, ati Jehosabadi ọmọ Ṣimiriti ará Moabu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 24

Wo Kronika Keji 24:26 ni o tọ