Kronika Keji 24:8 BM

8 Nítorí náà, ọba pàṣẹ pé kí wọ́n ṣe àpótí kan tí àwọn eniyan yóo máa sọ owó sí, kí wọ́n sì gbé e sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 24

Wo Kronika Keji 24:8 ni o tọ