Kronika Keji 25:10 BM

10 Nítorí náà Amasaya dá àwọn ọmọ ogun Efuraimu tí ó gbà pada sílé wọn. Nítorí náà, inú bí wọn gan-an sí Juda, wọ́n sì pada sílé pẹlu ìrúnú.

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:10 ni o tọ