Kronika Keji 25:20 BM

20 Ṣugbọn Amasaya kọ̀, kò gbọ́, nítorí pé Ọlọrun ni ó mú kí ọkàn rẹ̀ le, kí Ọlọrun lè fi Juda lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́ nítorí pé wọ́n ń bọ àwọn oriṣa Edomu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:20 ni o tọ