Kronika Keji 26:14 BM

14 Usaya ọba fún gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ ní apata, ọ̀kọ̀, àṣíborí, ẹ̀wù ihamọra, ọfà, ati òkúta fún kànnàkànnà wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:14 ni o tọ